Alphabeti

Today’s topic is ‘Alphabet Poem’ (A 26 line poem. With each line starting with a letter of the alphabet). I know I’m not such a good poet but I know I have to still carry on with this project. So I decided to reduce the number of people that can read my poem. Yoruba people…

(H)Enjoy!

Abike Omo Labinjo; Iyawo afesana Jimoh

Barawo aye ati orun.

Common insolent prostitute.

Daadaa ni mama e ko. Nkan Buruku lo ba tele.

Emi ki yo da bi Abike Labinjo.

Fesojaiye l’oruko mi. Aiye jeje ni mo n ba tele

Gun yan Gun yan ni mama Abike n se. Olode ni Baba e.

Honestly, Abike acts like her parents own the world.

Ibanuje ni fun omo ti o ba gboran si obi e lenu.

Jimoh ni anu mi n se.

Ko l’ogun arinya, on je ayan

Lodun to koja yi, Abike loyun fun omo kunrin Daniel, to wa lati Eko.

Mama Jimoh ko fun Jimoh lati gba omo yen.

Nise ni Jimoh gba iye re leti.

Omo mi, gboran simi lenu. Ma ti mi loju bi Abike. Ma pami lekun.

Pemi t’oba le fun e

Questions should not be asked about who you really are.

…………………………………………………………………………………………

Risikatu so fun mi pe o fe se ise dokita

Sugbon oko afesana e o gba fun

Ta lo l’aye Risikatu? Oko afesana re?

Umbrella ni ma fi gba ori Risikatu fun oro oshi yen.

Validation should not be sought for your convictions.

……………………………………………………………………………………………….

Wa, omo mi, simi, ko jeun daadaa ni gbogbo igba. Jeje laye. Aiye yi o le.

X-men, even, rest.

…………………………………………………………………………………………………

Yoruba ni French Tuntun.

Zobo is the new red wine.

 

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *